Connect with us

GospelMusic

Tope Alabi – Halleluyah

Halleluyah by Tope Alabi Mp3 Download

Get this song by Tope Alabi titled Halleluyah. Tope Alabi is a Nigerian gospel singer, film music composer and actress. She is also known as Ore ti o common and as Agbo Jesu. can be described as one of the pacesetters of soundtracks in the Yoruba film industry The song will make your playlist if love good music.

Use the link below to stream and download Halleluyah by Tope Alabi.

Lyrics Of Halleluyah by Tope Alabi

Hallelujah ni won ma koHallelujah si wo olurun miOrin hallelujah ni woo bawon torun ko o
Oju orun fun dedeAwo San man ni Pele ni peleEru lo fi ko ayeOkun fun ajaraEda o yanbo AwoEwo lo da Ara oto toMO korin hallelujah si wo tan awonOrun bo o
Mimo Mimo ni won keAwon ti Eda orun angeli lowo lowooWon fi ojo jo fi ori bale oAgba gba n ke MimoSi oludande aye gbogboHallelujah si oni ite ogo adituGbogboro owo to na aye ja lati inu orun wa Kikorin won o dake riSi olurun awon omo ogun
Hallelujah ni won koWon segun aye ko si daru dapoOwun gbo lo Leto letoEbi ko pa won ri beeni Ara ko ni won riKida ayo ekunrere alafiaAwa ti a le ke hallelujah ninu ayeAwa lafi Orin isegun se wa logoA o Jeri Ota a di Eni ite mole pataOrin hallelujah ni a fi ba Jesu jobaAwa ti a gbala
 

Download Mp3 Here

Click to comment

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Trending Music